0
Eko Ile - Fela Kuti
0 0

Eko Ile Fela Kuti

Eko Ile - Fela Kuti
[Chorus]
Ko ma si ibi ti mo le f'ori le
Kosi o
A'fe Eko ile
Ko ma si ibi ti mo le f'ori le oh
Ko si o
Afi Eko ile

[Verse 1]
Bi mo nba rajo lo London oh
Ma tun pada si Eko ile
Bi mo nba rajo si New York oh
Ma tun pada si Eko ile

[Refrain]
Eko o, Eko ile
Eko o, Eko ile

[Chorus]
Ko ma si ibi ti mo le f'ori le
Kosi o
A'fe Eko ile
Ko ma si ibi ti mo le f'ori le oh
Ko si o
Afi Eko ile
Comments (0)
The minimum comment length is 50 characters.
Information
There are no comments yet. You can be the first!
Login Register
Log into your account
And gain new opportunities
Forgot your password?