[Intro]
It's Nektunez, yeah
[Hook]
Ask about me, ask about me
Wọn ti lémí, but wọn ò múmí
Ọmọ Ọlọrun kọ́ lè súmí
Sẹ́kẹsẹ́kẹ búlà
I'm still getting my mulla
Dollar pẹ̀lú naira
Ikú tó pa iya teacher
Ó lè pa àwọn nigga
[Chorus]
Kíló n fò lókè ó (Fò lókè)
Ẹyẹ nìkan fò lókè ó (Fò lókè)
Kíló n rìn nílé (Rìn nílé)
Àwọn ẹ̀yàn ló máa n rìn nílé
Máté m’imọ̀lẹ̀ óòòòò
Máté ojú ilé mọ̀lẹ̀
Kọ́ mà bà dòbálè
Ìwọ ló máa fẹ́ kọ́lé
O ò fẹ́ kọ́lé
[Post-Chorus]
One man soldier
Mẹ́tà mẹ́tà gbọ́sà
Awilo Longomba
Fúńmi lọ́wọ́ mí biza
Kẹ́sẹ́kẹ́sẹ́ kàsà
Kàsàkàsà Blanca
I open Bible chapter
I step on the Satan
It's Nektunez, yeah
[Hook]
Ask about me, ask about me
Wọn ti lémí, but wọn ò múmí
Ọmọ Ọlọrun kọ́ lè súmí
Sẹ́kẹsẹ́kẹ búlà
I'm still getting my mulla
Dollar pẹ̀lú naira
Ikú tó pa iya teacher
Ó lè pa àwọn nigga
[Chorus]
Kíló n fò lókè ó (Fò lókè)
Ẹyẹ nìkan fò lókè ó (Fò lókè)
Kíló n rìn nílé (Rìn nílé)
Àwọn ẹ̀yàn ló máa n rìn nílé
Máté m’imọ̀lẹ̀ óòòòò
Máté ojú ilé mọ̀lẹ̀
Kọ́ mà bà dòbálè
Ìwọ ló máa fẹ́ kọ́lé
O ò fẹ́ kọ́lé
[Post-Chorus]
One man soldier
Mẹ́tà mẹ́tà gbọ́sà
Awilo Longomba
Fúńmi lọ́wọ́ mí biza
Kẹ́sẹ́kẹ́sẹ́ kàsà
Kàsàkàsà Blanca
I open Bible chapter
I step on the Satan
Comments (0)
The minimum comment length is 50 characters.