0
Iya Alariya - 9ice
0 0

Iya Alariya 9ice

Iya Alariya - 9ice
[Chorus]
Emi ni kan kan mowa
Moni baba ni igbejo
Mo wowo ra
Mo gbagbe iyin ola ati egan
Iya alariya ken ken, eh-eh
Iya alariya ken ken, eh-eh
Iya alariya ken ken, ma jo mayo
Iya alariya ken ken, eh-eh

[Verse 1]
Ti moba lo, pelu imo kan
Taabi mo re koja lo, pelu inu kan
Sa dede ni blessing awa si odo mi tori mo gbagbo
Egbegberun subun, lotun losi mi
Nkan kan koni se omo olorun
Okeere opoju temi
Emi ni kankan mowa
Moni baba ni igbejo

[Chorus]
Emi ni kan kan mowa
Moni baba ni igbejo
Mo wowo ra
Mo gbagbe iyin ola ati egan
Iya alariya ken ken, eh-eh
Iya alariya ken ken, eh-eh
Iya alariya ken ken, ma jo mayo
Iya alariya kеn ken, eh-eh
Comments (0)
The minimum comment length is 50 characters.
Information
There are no comments yet. You can be the first!
Login Register
Log into your account
And gain new opportunities
Forgot your password?