(2T Uponthebeat)
Qdot l'oruko mi
Omo'mo Moriamo
Omo o le buru titi, k'afi f'ekun pa je
E bami gbe Oluwa tobi, Lekan ti yi pada
Ko mu'gbo mo (Loud lon fa)
Ko fa cigar (Shisha lon fa)
Ko gba Jedi (Molly lon gba)
T'oba ti gb'oja, ma na soldier
Ko mu'gbo mo oh (Loud lon fa)
Ko fa cigar (Shisha lon fa)
Ko gba Jedi (Molly lon gba)
T'oba ti gb'oja, ma na soldier
(Otilo)
Owo t'oba wo "wan-wan" (otilo)
Oole t'oba wo'nu Eko (otilo)
Ajawo yin (otilo)
Iyawo yin (otilo)
L'ati Mainland (otilo)
Ma bo ni Lekki (otilo)
Lekki ninu loh loh (otilo)
A ma shey Uber fun (otilo)
A ma shey Utuba fun (otilo)
Tal'efin ta'yin? (otilo)
Ab'ori nta yin? (otilo)
Iyawo oga yin (otilo)
Iyawo egbon yin (otilo)
T'oba ti fi si (otilo)
Won ba pada yo-o (otilo)
Omo t'en gbe wa (otilo)
Awa l'agbe lo oh (otilo)
Okada l'efi gbe wa (otilo)
Benz l'afi gbe lo oh (otilo)
A ma ra Fendi fun (otilo)
A ma ra Gucci fun (otilo)
T'oba ti g'eshin kutakuta (otilo)
Kole mo'na ile mo (otilo)
Ma bo l'odo Gattuso (otilo)
Elegushi wo'nu Oniru (otilo)
T'omo ti mu Azul (otilo)
E wa ni "k'oma ba sun" (otilo)
Fa-la-ti-do (otilo)
Re-mi-re-do (otilo)
So-so-mi-re-do-do (otilo)
Fa-so-mi-la-ti-do (otilo)
Qdot l'oruko mi
Omo'mo Moriamo
Omo o le buru titi, k'afi f'ekun pa je
E bami gbe Oluwa tobi, Lekan ti yi pada
Ko mu'gbo mo (Loud lon fa)
Ko fa cigar (Shisha lon fa)
Ko gba Jedi (Molly lon gba)
T'oba ti gb'oja, ma na soldier
Ko mu'gbo mo oh (Loud lon fa)
Ko fa cigar (Shisha lon fa)
Ko gba Jedi (Molly lon gba)
T'oba ti gb'oja, ma na soldier
(Otilo)
Owo t'oba wo "wan-wan" (otilo)
Oole t'oba wo'nu Eko (otilo)
Ajawo yin (otilo)
Iyawo yin (otilo)
L'ati Mainland (otilo)
Ma bo ni Lekki (otilo)
Lekki ninu loh loh (otilo)
A ma shey Uber fun (otilo)
A ma shey Utuba fun (otilo)
Tal'efin ta'yin? (otilo)
Ab'ori nta yin? (otilo)
Iyawo oga yin (otilo)
Iyawo egbon yin (otilo)
T'oba ti fi si (otilo)
Won ba pada yo-o (otilo)
Omo t'en gbe wa (otilo)
Awa l'agbe lo oh (otilo)
Okada l'efi gbe wa (otilo)
Benz l'afi gbe lo oh (otilo)
A ma ra Fendi fun (otilo)
A ma ra Gucci fun (otilo)
T'oba ti g'eshin kutakuta (otilo)
Kole mo'na ile mo (otilo)
Ma bo l'odo Gattuso (otilo)
Elegushi wo'nu Oniru (otilo)
T'omo ti mu Azul (otilo)
E wa ni "k'oma ba sun" (otilo)
Fa-la-ti-do (otilo)
Re-mi-re-do (otilo)
So-so-mi-re-do-do (otilo)
Fa-so-mi-la-ti-do (otilo)
Comments (0)
The minimum comment length is 50 characters.