0
Happy People - Aṣa
0 0

Happy People Aṣa

Happy People - Aṣa
O òré mi Láídé
Níbo ló dà l'ójó Saturday yìí
Hmmm... Wón se party níhìn o
L'Ókè súnáà léhìn kùlé àwon Làtí

Ànkárá la dá
Kòstúmù la wò
Kosé l'afi gbóyàn sókè
Bàtà mí ti ready

Ànkárá la dá
Kòstúmù la wò
Kosé l'afi gbóyàn sókè
Bàtà mí ti ready

Oh we're happy people
And that's who we are
We're having fun
We're the children of the sun

Oh we're happy people
And that's who we are
We don't care
We're the children of the sun

O òré mi Laide
Níbo ló kàn l'ójó Sunday yìí
Hmmm... Wón gbéyàwó níhin o
L'Ókè pópó légbe ilé àwon Toyeeb
Comments (0)
The minimum comment length is 50 characters.
Information
There are no comments yet. You can be the first!
Login Register
Log into your account
And gain new opportunities
Forgot your password?