0
Olorun - Asake
0 0

Olorun Asake

Olorun - Asake
[Intro]
Ololade mi Aşakę
Emi kọ, Olọrun ma ni
Emi kọ, Olọrun ma ni
Awa kọ, ọ ọ
Emi kọ o
Olọrun ma ni

[Pre-Chorus]
Ta lo gbọn t'Olorun? (Ọmọ ọgbọn)
Ko si anybody t'o l'ogbon t'Olorun
Ti wọn ba buga ẹ o, ya gba fun Olorun
Awọn ti wọn buga mi, wọn ti sa pamọ
Wọn ti sa pamọ

[Chorus]
Emi kọ o, o, Olọrun ma ni o (Ọlọrun ma ni o)
Emi kọ o, o, Olọrun ma ni o (Olorun ma ni o)
Awa kọ, ọ, Ọlọrun ma ni o (Oh oh oh)
Emi kọ o, Olọrun ma ni o

[Verse]
Ọmọ no be me, şebi na God
Carry me from down straight to the top
2020 was real-tough
Fall for ground, almost gave up (Gave up)
Mo fun won l'Omọ Ope mo dę ję lo o
Go naked in my room, I speak to God
Baba God, I no sabi all
So guide me, as I dey move on on on on
Comments (0)
The minimum comment length is 50 characters.
Information
There are no comments yet. You can be the first!
Login Register
Log into your account
And gain new opportunities
Forgot your password?