Ojúmọ́ ti mọ́, ojúmọ́ ti mọ́ mi
Nílẹ̀ yìí o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o
Ojúmọ́ ti mọ́, ojúmọ́ ti mọ́ mi
Nílẹ̀ yìí o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà
Ẹyẹ àdàbà tí ń fò lókèlókè
Wá bà lé mi o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o
Ojúmọ́ ti mọ́, ojúmọ́ ti mọ́ mi
Nílẹ̀ yìí o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o
Ojúmọ́ ti mọ́, ojúmọ́ ti mọ́ mi
Nílẹ̀ yìí o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o, ó yá!
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà, e e e
Ẹyẹ àdàbà tí ń fò lókèlókè
Wá bà lé mi o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o, ó yá!
Nílẹ̀ yìí o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o
Ojúmọ́ ti mọ́, ojúmọ́ ti mọ́ mi
Nílẹ̀ yìí o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà
Ẹyẹ àdàbà tí ń fò lókèlókè
Wá bà lé mi o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o
Ojúmọ́ ti mọ́, ojúmọ́ ti mọ́ mi
Nílẹ̀ yìí o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o
Ojúmọ́ ti mọ́, ojúmọ́ ti mọ́ mi
Nílẹ̀ yìí o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o, ó yá!
Ẹyẹ àdàbà, ẹyẹ àdàbà, e e e
Ẹyẹ àdàbà tí ń fò lókèlókè
Wá bà lé mi o
Ojúmọ́ ti mọ́, mo ríre o, ó yá!
Comments (0)
The minimum comment length is 50 characters.